Samuẹli Kinni 26:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n pabùdó wọn sí ẹ̀bá ọ̀nà ní òkè Hakila, Dafidi sì wà ninu aṣálẹ̀ náà. Nígbà tí Dafidi mọ̀ pé Saulu ń wá òun kiri,

Samuẹli Kinni 26

Samuẹli Kinni 26:1-7