Samuẹli Kinni 26:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi dáhùn pé, “Ọ̀kọ̀ rẹ nìyí, oluwa mi, jẹ́ kí ọ̀kan ninu àwọn ọmọ ogun rẹ wá gbà á.

Samuẹli Kinni 26

Samuẹli Kinni 26:16-25