Samuẹli Kinni 26:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi dáhùn pé, “Ǹjẹ́ ìwọ kọ́ ni alágbára jùlọ ní Israẹli? Kí ló dé tí o kò dáàbò bo ọba, oluwa rẹ? Láìpẹ́ yìí ni ẹnìkan wọ inú àgọ́ yín láti pa oluwa rẹ.

Samuẹli Kinni 26

Samuẹli Kinni 26:5-19