Samuẹli Kinni 25:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní kí wọ́n kí i báyìí pé, “Alaafia fún ọ, ati fún ilé rẹ ati fún gbogbo ohun tí o ní.

Samuẹli Kinni 25

Samuẹli Kinni 25:1-12