Samuẹli Kinni 25:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Abigaili pada dé ilé ó bá Nabali ninu àsè bí ọba. Inú rẹ̀ dùn nítorí pé ó ti mu ọtí ní àmupara. Abigaili kò sì sọ nǹkankan fún un títí di òwúrọ̀ ọjọ́ keji.

Samuẹli Kinni 25

Samuẹli Kinni 25:29-43