Samuẹli Kinni 25:31 BIBELI MIMỌ (BM)

o kò ní ní ìbànújẹ́ ọkàn pé o ti paniyan rí láìnídìí tabi pé o ti gbẹ̀san ara rẹ. Nígbà tí OLUWA bá sì bukun ọ, jọ̀wọ́ má ṣe gbàgbé èmi iranṣẹbinrin rẹ.”

Samuẹli Kinni 25

Samuẹli Kinni 25:21-39