Samuẹli Kinni 25:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Jọ̀wọ́ gba ẹ̀bùn tí èmi iranṣẹbinrin rẹ mú wá fún ọ kí o sì fi fún àwọn ọkunrin tí wọ́n tẹ̀lé ọ.

Samuẹli Kinni 25

Samuẹli Kinni 25:26-34