Samuẹli Kinni 25:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀kan ninu àwọn ọdọmọkunrin Nabali sọ fún Abigaili, iyawo Nabali pé, “Dafidi rán àwọn iranṣẹ láti aṣálẹ̀ wá sọ́dọ̀ oluwa wa, ṣugbọn ó kanra mọ́ wọn.

Samuẹli Kinni 25

Samuẹli Kinni 25:6-16