Samuẹli Kinni 25:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Samuẹli kú, gbogbo àwọn ọmọ Israẹli kó ara wọn jọ láti ṣọ̀fọ̀ rẹ̀. Wọ́n sì sin òkú rẹ̀ sí ilé rẹ̀ ní Rama.Lẹ́yìn náà, Dafidi lọ sí aṣálẹ̀ Parani.

Samuẹli Kinni 25

Samuẹli Kinni 25:1-8