Samuẹli Kinni 24:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu mú ẹgbẹẹdogun (3,000) akọni ọmọ ogun lára àwọn ọmọ ogun Israẹli, wọ́n lọ láti wá Dafidi ati àwọn eniyan rẹ̀ ní orí àwọn àpáta ewúrẹ́ ìgbẹ́.

Samuẹli Kinni 24

Samuẹli Kinni 24:1-5