Samuẹli Kinni 24:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí OLUWA dájọ́ láàrin èmi pẹlu rẹ, kí ó gba ọ̀rọ̀ náà yẹ̀wò, kí ó gbèjà mi, kí ó sì gbà mí, lọ́wọ́ rẹ.”

Samuẹli Kinni 24

Samuẹli Kinni 24:13-21