Samuẹli Kinni 24:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí OLUWA dájọ́ láàrin èmi pẹlu rẹ. Kí ó sì jẹ ọ́ níyà fún ìwà burúkú tí ò ń hù sí mi, nítorí pé n kò ní ṣe ọ́ ní ibi kan.

Samuẹli Kinni 24

Samuẹli Kinni 24:6-14