Samuẹli Kinni 23:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá pada sí Sifi ṣáájú Saulu. Ṣugbọn Dafidi ati àwọn ọkunrin rẹ̀ ti wà ní aṣálẹ̀ Maoni tí ó wà ní Araba lápá ìhà gúsù Jeṣimoni.

Samuẹli Kinni 23

Samuẹli Kinni 23:20-25