Samuẹli Kinni 23:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, Dafidi ati ẹgbẹta (600) àwọn ọkunrin tí wọ́n wà pẹlu rẹ̀ kúrò ní Keila lẹsẹkẹsẹ. Nígbà tí Saulu gbọ́ pé Dafidi ti kúrò ní Keila, kò lọ gbógun ti Keila mọ́.

Samuẹli Kinni 23

Samuẹli Kinni 23:12-17