Samuẹli Kinni 22:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ahimeleki bá a ṣe ìwádìí lọ́dọ̀ OLUWA, lẹ́yìn náà ó fún Dafidi ní oúnjẹ ati idà Goliati, ará Filistia.”

Samuẹli Kinni 22

Samuẹli Kinni 22:6-15