Samuẹli Kinni 21:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi tún bèèrè lọ́wọ́ Ahimeleki pé, “Ǹjẹ́ o ní ọ̀kọ̀ tabi idà kí o fún mi? Ìkánjú tí mo fi kúrò nílé kò jẹ́ kí n ranti mú idà tabi ohun ìjà kankan lọ́wọ́.”

Samuẹli Kinni 21

Samuẹli Kinni 21:1-13