Samuẹli Kinni 20:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Jonatani tún sọ fún un pe, “Yára má ṣe dúró.” Ọmọ náà ṣa àwọn ọfà náà, ó sì pada sọ́dọ̀ ọ̀gá rẹ̀,

Samuẹli Kinni 20

Samuẹli Kinni 20:36-42