Samuẹli Kinni 20:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sọ fún ọmọ náà pé, “Sáré lọ wá àwọn ọfà tí mo ta wá.” Bí ọmọ náà ti ń sáré lọ, Jonatani ta ọfà siwaju rẹ̀.

Samuẹli Kinni 20

Samuẹli Kinni 20:26-42