Samuẹli Kinni 20:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu bá ju ọ̀kọ̀ rẹ̀ mọ́ ọn, ó fẹ́ pa á. Nígbà náà ni Jonatani mọ̀ dájú pé, baba òun pinnu láti pa Dafidi.

Samuẹli Kinni 20

Samuẹli Kinni 20:27-37