Samuẹli Kinni 20:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ keji àjọ̀dún oṣù tuntun, ìjókòó Dafidi tún ṣófo. Nígbà náà ni Saulu bèèrè lọ́wọ́ Jonatani pé, “Kí ló dé tí ọmọ Jese kò wá sí ibi oúnjẹ lánàá ati lónìí?”

Samuẹli Kinni 20

Samuẹli Kinni 20:21-34