Samuẹli Kinni 20:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí mo bá sọ fún un pé, ‘Wo àwọn ọfà náà níwájú rẹ,’ máa bá tìrẹ lọ nítorí OLUWA ni ó fẹ́ kí o lọ.

Samuẹli Kinni 20

Samuẹli Kinni 20:12-29