Samuẹli Kinni 20:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Jonatani dá a lóhùn pé, “Kí á má rí i, o kò ní kú. Kò sí nǹkankan ti baba mi ń ṣe, bóyá ńlá tabi kékeré, tí kì í sọ fún mi; kò sì tíì sọ èyí fún mi, nítorí náà ọ̀rọ̀ náà kò rí bẹ́ẹ̀.”

Samuẹli Kinni 20

Samuẹli Kinni 20:1-10