Samuẹli Kinni 20:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí wọn kò bá rí ọ ní ọjọ́ keji, wọn yóo mọ̀ dájú pé o kò sí láàrin wọn. Nítorí náà, lọ sí ibi tí o farapamọ́ sí ní ìjelòó, kí o sì farapamọ́ sẹ́yìn àwọn òkúta ọ̀hún nnì.

Samuẹli Kinni 20

Samuẹli Kinni 20:17-25