Samuẹli Kinni 2:7 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ni ó lè sọni di aláìní,òun náà ni ó sì lè sọ eniyan di ọlọ́rọ̀.Òun ni ó ń gbéni ga,òun náà ni ó sì ń rẹ eniyan sílẹ̀.

Samuẹli Kinni 2

Samuẹli Kinni 2:1-8