Samuẹli Kinni 2:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kan náà ni àwọn ọmọ rẹ mejeeji, Hofini ati Finehasi, yóo kú. Èyí ni yóo jẹ́ àmì fún ọ pé gbogbo ohun tí mo sọ ni yóo ṣẹ.

Samuẹli Kinni 2

Samuẹli Kinni 2:26-36