Má sọ̀rọ̀ pẹlu ìgbéraga mọ́,má jẹ́ kí ọ̀rọ̀ ìgbéraga ti ẹnu rẹ jáde,nítorí Ọlọrun tí ó mọ ohun gbogbo ni OLUWA,gbogbo ohun tí ẹ̀dá bá ṣe ni ó sì máa ń gbéyẹ̀wò.