Samuẹli Kinni 2:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀ṣẹ̀ tí àwọn ọmọ Eli ń dá yìí burú pupọ lójú OLUWA, nítorí pé wọn kò náání ẹbọ OLUWA.

Samuẹli Kinni 2

Samuẹli Kinni 2:10-21