Samuẹli Kinni 19:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ogun tún bẹ́ sílẹ̀ láàrin àwọn Filistini ati Israẹli. Dafidi kọlu àwọn Filistini, ó pa pupọ ninu wọn tóbẹ́ẹ̀ tí àwọn Filistini fi sá lójú ogun.

Samuẹli Kinni 19

Samuẹli Kinni 19:1-17