Samuẹli Kinni 19:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó fi ẹ̀mí ara rẹ̀ wéwu láti pa Goliati, OLUWA sì ṣẹ́ ogun ńlá fún Israẹli. Nígbà tí o rí i inú rẹ dùn. Kí ló dé tí o fi ń wá ọ̀nà láti pa Dafidi láìṣẹ̀?”

Samuẹli Kinni 19

Samuẹli Kinni 19:1-14