Samuẹli Kinni 19:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Òun pàápàá dìde ó lọ sí Rama. Nígbà tí ó dé etí kànga jíjìn tí ó wà ní Seku, ó bèèrè ibi tí Samuẹli ati Dafidi wà. Wọ́n sì sọ fún un wí pé, wọ́n wà ní Naioti ti Rama.

Samuẹli Kinni 19

Samuẹli Kinni 19:15-24