Samuẹli Kinni 18:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n sọ èyí fún Dafidi, ó dá wọn lóhùn pé, “Kì í ṣe nǹkan kékeré ni láti jẹ́ àna ọba, talaka ni mí, èmi kì í sì í ṣe eniyan pataki.”

Samuẹli Kinni 18

Samuẹli Kinni 18:22-30