Samuẹli Kinni 18:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu mú un kúrò lọ́dọ̀ ara rẹ̀, ó fi ṣe olórí ẹgbẹrun ọmọ ogun, Dafidi sì ń darí àwọn ọmọ ogun rẹ̀.

Samuẹli Kinni 18

Samuẹli Kinni 18:6-23