Samuẹli Kinni 17:58 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu bi í léèrè pé, “Ọmọ, ta ni baba rẹ?”Dafidi dáhùn pé, “Ọmọ Jese ni mí, iranṣẹ rẹ, tí ń gbé Bẹtilẹhẹmu.”

Samuẹli Kinni 17

Samuẹli Kinni 17:55-58