Samuẹli Kinni 17:42 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó rí Dafidi dáradára, ó wò ó pé ọmọ kékeré kan lásán, tí ó tóbi tí ó sì lẹ́wà ni, nítorí náà, ó fojú tẹmbẹlu rẹ̀.

Samuẹli Kinni 17

Samuẹli Kinni 17:33-43