Samuẹli Kinni 17:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu bá sọ fún Dafidi pé, “O kò lè bá Filistini yìí jà, nítorí pé ọmọde ni ọ́, òun sì ti jẹ́ jagunjagun láti ìgbà èwe rẹ̀ wá.”

Samuẹli Kinni 17

Samuẹli Kinni 17:32-38