Samuẹli Kinni 17:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu ọba, ati àwọn ẹ̀gbọ́n Dafidi ati àwọn ọmọ ogun yòókù wà ní àfonífojì Ela níbi tí wọ́n ti ń bá àwọn Filistini jà.

Samuẹli Kinni 17

Samuẹli Kinni 17:16-21