Samuẹli Kinni 17:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Odidi ogoji ọjọ́ ni Goliati fi pe àwọn ọmọ ogun Israẹli níjà ní àràárọ̀ ati ìrọ̀lẹ́ ìrọ̀lẹ́.

Samuẹli Kinni 17

Samuẹli Kinni 17:9-24