Samuẹli Kinni 16:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà Jese sọ fún Ṣama pé kí ó kọjá níwájú Samuẹli. Samuẹli tún ní, “OLUWA kò yan eléyìí náà.”

Samuẹli Kinni 16

Samuẹli Kinni 16:2-11