Samuẹli Kinni 16:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Pe Jese wá sí ibi ẹbọ náà, n óo sì sọ ohun tí o óo ṣe fún ọ. N óo dárúkọ ẹnìkan fún ọ, ẹni náà ni kí o fi jọba.”

Samuẹli Kinni 16

Samuẹli Kinni 16:1-7