Samuẹli Kinni 16:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Jese ranṣẹ lọ mú un wá. Ọmọ náà jẹ́ ọmọ pupa, ojú rẹ̀ dára ó sì lẹ́wà. OLUWA wí fún Samuẹli pé, “Dìde, kí o ta òróró sí i lórí nítorí pé òun ni mo yàn.”

Samuẹli Kinni 16

Samuẹli Kinni 16:10-18