Samuẹli Kinni 15:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó mú Agagi, ọba àwọn ará Amaleki láàyè, ó sì fi idà pa gbogbo àwọn eniyan rẹ̀.

Samuẹli Kinni 15

Samuẹli Kinni 15:5-10