Samuẹli Kinni 15:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu dá a lóhùn pé, “Mo ti pa òfin OLUWA mọ́, mo jáde lọ bí o ti wí fún mi pé kí n jáde lọ, mo mú Agagi ọba pada bọ̀, mo sì pa gbogbo àwọn ará Amaleki run.

Samuẹli Kinni 15

Samuẹli Kinni 15:11-24