Samuẹli Kinni 15:2 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA àwọn ọmọ ogun ní, ‘N óo jẹ àwọn ará Amaleki níyà nítorí pé wọ́n gbógun ti àwọn ọmọ Israẹli, nígbà tí wọ́n ń bọ̀ láti Ijipti.

Samuẹli Kinni 15

Samuẹli Kinni 15:1-9