Samuẹli Kinni 15:11 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ó dùn mí pé mo fi Saulu jọba. Ó ti yipada kúrò lẹ́yìn mi, kò sì pa òfin mi mọ́.” Inú bí Samuẹli, ó sì gbadura sí OLUWA ní gbogbo òru ọjọ́ náà.

Samuẹli Kinni 15

Samuẹli Kinni 15:9-13