Samuẹli Kinni 14:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí wọ́n bá ní kí á dúró kí àwọn tọ̀ wá wá, a óo dúró níbi tí a bá wà, a kò ní lọ sọ́dọ̀ wọn.

Samuẹli Kinni 14

Samuẹli Kinni 14:8-19