Samuẹli Kinni 14:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọdọmọkunrin náà dá a lóhùn pé, “Ohunkohun tí ọkàn rẹ bá fẹ́ ni kí o ṣe. Mo wà lẹ́yìn rẹ, bí ọkàn rẹ ti rí ni tèmi náà rí.”

Samuẹli Kinni 14

Samuẹli Kinni 14:1-9