Samuẹli Kinni 14:51-52 BIBELI MIMỌ (BM)

51. Kiṣi ni baba Saulu. Neri, baba Abineri jẹ́ ọmọ Abieli.

52. Gbogbo ọjọ́ ayé Saulu ni ó fi bá àwọn ará Filistia jagun kíkankíkan. Nígbà gbogbo tí Saulu bá sì ti rí ọkunrin tí ó jẹ́ alágbára tabi akikanju, a máa fi kún àwọn ọmọ ogun rẹ̀.

Samuẹli Kinni 14