Samuẹli Kinni 14:50 BIBELI MIMỌ (BM)

Ahinoamu ọmọ Ahimaasi ni aya Saulu. Abineri ọmọ Neri, arakunrin baba Saulu, sì ni balogun rẹ̀.

Samuẹli Kinni 14

Samuẹli Kinni 14:46-52