Samuẹli Kinni 14:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Èyí ekinni wà ní apá àríwá ọ̀nà náà, ó dojú kọ Mikimaṣi. Ekeji sì wà ní apá gúsù, ó dojú kọ Geba.

Samuẹli Kinni 14

Samuẹli Kinni 14:4-8