Samuẹli Kinni 14:48 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó jagun gẹ́gẹ́ bí akikanju, ó ṣẹgun àwọn ará Amaleki. Ó sì gba Israẹli kalẹ̀ lọ́wọ́ àwọn tí wọn ń fi ogun kó wọn.

Samuẹli Kinni 14

Samuẹli Kinni 14:41-52